Iṣẹ́ Ìwàásù Wa
IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìṣẹ́ Ìwàásù ní Agbègbè Àdádó—Ireland
Ìdílé kan sọ bí wọ́n ṣe túbọ̀ sún mọ́ra nígbà tí wọ́n lọ wàásù ní agbègbè tó wà ní àdádó.
IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìṣẹ́ Ìwàásù ní Agbègbè Àdádó—Ireland
Ìdílé kan sọ bí wọ́n ṣe túbọ̀ sún mọ́ra nígbà tí wọ́n lọ wàásù ní agbègbè tó wà ní àdádó.
Àkànṣe Ìwàásù Yọrí sí Rere ní Lapland
Kà nípa bí àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Lapland ṣe tẹ́wọ́ gba ohun táwọn Ẹlẹ́rìí sapá lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ láti ṣe kí wọ́n lè ràn wọ́n lọ́wọ́.
Àwọn Àtẹ Ìwé Tó Ṣeé Tì Kiri “Lọ Lo Àkókò Ìsinmi” ní Jámánì
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń lo àwọn àtẹ ìwé tó ṣeé tì kiri sáwọn ìlú bíi Berlin, Cologne, Hamburg, Munich àtàwọn ìlú míì. Ṣé àwọn àtẹ ìwé yìí máa ríṣẹ́ ṣe níbi táwọn ọmọ ilẹ̀ Jámánì ti lọ lo àkókò ìsinmi?
Wọ́n Pàtẹ “Ẹ̀bùn tí Ọlọ́run Fún Àwọn Èèyàn” ní Ìlú Ìṣúra
Àwọn Bíbélì, àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì àtàwọn fídíò táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà pàtẹ síbi ìpàtẹ ìwé Gaudeamus tó wáyé lórílẹ̀-èdè Ròmáníà wú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àtàwọn olùkọ́ lórí.
Wọ́n Wàásù fún Àwọn Sinti àti Àwọn Roma Lórílẹ̀-èdè Jámánì
Nígbà àkànṣe ìwàásù táwọn Ẹlẹ́rìí ṣe lọ́dún 2016, wọ́n pín àṣàrò kúkúrú tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó 3,000, wọ́n bá àwọn Sinti àti Roma tó lé ní 360 sọ̀rọ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn 19 lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.
Wọ́n Pàtẹ Ìṣúra Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ ní Botswana
Fídíò bèbí tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà gbàfiyèsí àwọn ọmọdé. Ọ̀wọ́ àwọn fídíò yìí máa ń jẹ́ kéèyàn rí béèyàn ṣe lè máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Bíbélì.
Àwọn Tó Ń Rìnrìn Àjò Lórí Òkun Ń Gbọ́ Ìròyìn Ayọ̀
Kí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lè wàásù fáwọn tó ń rìnrìn àjò káàkiri lórí òkun, wọ́n ti ṣètò bí wọ́n á ṣe máa kọ́ àwọn yìí lẹ́kọ̀ọ́ láwọn ibùdókọ̀ ńlá. Báwo ló ṣe rí lára àwọn awakọ̀ òkun tí wọ́n bá sọ̀rọ̀?
Wọ́n Kéde Ohun tí Bíbélì Sọ Nílùú Paris
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ìwàásù àkànṣe kan láti kéde ohun tí wọ́n gbà gbọ́ pé Bíbélì sọ nípa ìgbà tí àwọn èèyàn ò ní ṣe ohun tó ń ba àyíká jẹ́ mọ́.
Àwọn Ọmọ Ìbílẹ̀ Amẹ́ríkà Gbọ́ Tuntun Níbi tí Wọ́n Ti Ń Ṣayẹyẹ Nílùú New York
Àwọn ìwé ìròyìn tó wà láwọn èdè ìbílẹ̀ Amẹ́ríkà táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà pàtẹ níbi ayẹyẹ ‘Gateway to Nations’ tó wáyé lọ́dún 2015 wú àwọn èèyàn lórí gan-an.
Ìwàásù Ìjọba Ọlọ́run Dé Àwọn Àgbègbè Àdádó
Láìka àwọn ìṣòro tá a ní sí, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lo ọ̀pọ̀ àkókò ní àwọn àgbègbè àdádó láti kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.
Iṣẹ́ Ìwàásù Ní Àwọn Ìgbèríko Lórílẹ̀-Èdè Kánádà
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà wàásù fún àwọn tó wà ní ìgbèríko lédè ìbílẹ̀ wọn kí gbogbo wọ́n lè gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.
Wọ́n Rìn Gba Àárín Òkun Kọjá Láti Lọ Wàásù
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ọ̀nà kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀ tá a fi lè lọ wàásù fún àwọn tó ń gbé ní erékùṣù kan tí wọ́n ń pè ní Halligen.
Wíwàásù ní Agbègbè Àdádó—Ọsirélíà
Wo bí ìdílé Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ṣe gbádùn ọ̀sẹ̀ alárinrin tí wọ́n fi rìnrìn-àjò lọ sí ìgbèríko kan nílẹ̀ Ọsirélíà kí wọ́n lè lọ kọ́ àwọn èèyàn ibẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.
Bí A Ṣe Lè Fi Ìkànnì JW.ORG Wàásù Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, lọ́mọdé àti lágbà fẹ́ràn láti máa fi ìkànnì wọn tí wọ́n ṣe àtúntò rẹ̀ wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run fún ọ̀pọ̀ èèyàn bó bá ti lè ṣeé ṣe tó.