Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Yàtọ̀ sí àwọn ìlànà tá à ń tẹ̀ lé kárí ayé, wàá rí ìlànà míì tó wà fún àwọn orílẹ̀-èdè pàtó kan nínú abala Lílo Ìsọfúnni Ẹni ti orílẹ̀-èdè tó o bá yàn. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, yan orílẹ̀-èdè kan nínú àwọn tá a tò sí ìsàlẹ̀ yìí.