ÌKÀNNÌ JW.ORG
Fi Ìlujá Àpilẹ̀kọ, Fídíò Tàbí Ìtẹ̀jáde Kan Ránṣẹ́ Lórí JW.ORG
O lè fi ìlujá àpilẹ̀kọ, fídíò tàbí ìtẹ̀jáde tó wà lórí jw.org ránṣẹ́ sí ẹnì kan tó o bá tẹ àmì “Fi ránṣẹ́”. O lè fi ránṣẹ́ lórí e-mail tàbí kó o ṣe ẹ̀dà rẹ̀ sínú àtẹ̀jíṣẹ́ tó o fẹ́ fi ránṣẹ́.