JW LIBRARY
Ìrànlọ́wọ́ Lórí Windows
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe ètò ìṣiṣẹ́ JW Library. Oríṣiríṣi ìtumọ̀ Bíbélì ló wà lórí ẹ̀, tó fi mọ́ àwọn ìwé ńlá àtàwọn ìwé pẹlẹbẹ tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.
Ohun Tuntun
October 2021 (Version 12.5)
Wàá lè wa Ìwé Ìwádìí tuntun jáde lábẹ́ abala ìwádìí nínú Bíbélì
ÀKÍYÈSÍ: Version 12.5 ni ètò ìṣiṣẹ́ JW Library tó máa Windows 10 versions 1709, 1803 àti 1809 ṣiṣẹ́ kẹ́yìn. Tó bá jẹ́ àwọn Windows tó ti pẹ́ yìí ni ẹ̀rọ rẹ ń lò, ó máa nílò láti jẹ́ kí Windows yẹn gbé pẹ́ẹ́lí sí i kó o lè rí àwọn ohun tuntun tó máa jáde lórí JW Library lọ́jọ́ iwájú wà jáde.
July 2021 (Version 12.4)
O ti lè yan èdè tó o fẹ́ kí Ìròyìn Tuntun máa jẹ́.
O lè fi ìlujá sí Ẹsẹ Ojúmọ́ àti Ìpàdé ráńṣẹ́ sí àwọn míì.
Ó ti wá túbọ̀ rọrùn láti rí ìsọfúnni nípa àwọn ìtẹ̀jáde tá a ti ṣe àtúnṣe sí.
January 2021 (Version 12.3)
A ti ṣe àtúnṣe sí bí a ṣe kọ àwọn lẹ́tà kó lè túbọ̀ rọrùn láti kà, kó sì rí bó ṣe rí lórí ìkànnì jw.org.
NÍ APÁ YÌÍ
Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Lo JW Library—Windows
Learn how to use the main features of JW Library on Windows devices.
Bó O Ṣe Lè Wa Bíbélì Jáde Kó O sì Máa Lò Ó—Windows
Kọ́ bó o ṣe lè wa Bíbélì jáde lórí JW Library, kó o sì máa lò ó lórí àwọn fóònù Windows.
Bó O Ṣe Lè Wa Ìwé Jáde Kó O sì Máa Lò Ó—Lórí Windows
Kọ́ bó o ṣe lè wa ìwé jáde lórí JW Library, kó o sì máa lò ó lórí àwọn fóònù Windows.
Bó O Ṣe Lè Sàmì sí Ìwé—Lórí Windows
Kọ́ bó o ṣe lè máa sàmì sí ìwé nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.
Wo Àwọn Ohun Tó O Ti Kà Tẹ́lẹ̀—Lórí Windows
Kọ́ bó o ṣe lè wo àwọn ohun tó o ti kà tẹ́lẹ̀ nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.
Pinnu Bó O Ṣe Fẹ́ Kí Ìwé Tó Ò Ń Kà Rí—Lórí Windows
Kọ́ bó o ṣe lè ṣe é kí ìwé tó ò ń kà nínú JW Library rí bó o ṣe fẹ́ kó rí lórí àwọn fóònù Windows.
Wá Ọ̀rọ̀ Nínú Bíbélì Tàbí Nínú Ìwé—Lórí Windows
Kọ́ bó o ṣe lè wá ọ̀rọ̀ nínú Bíbélì tàbí ìwé, kó o sì tún wá àkòrí ọ̀rọ̀ ní Insight on the Scriptures nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.
Bó O Ṣe Lè Kun Ọ̀rọ̀—Lórí Windows
Kọ́ bó o ṣe lè kun ọ̀rọ̀ nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.
Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè—JW Library (Lórí Windows)
Wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè.