Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JUNE 16, 2021
RỌ́ṢÍÀ

Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Russia Fagi Lé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn tí Arákùnrin Sergey Verkhoturov Pè

Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Russia Fagi Lé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn tí Arákùnrin Sergey Verkhoturov Pè

Ní June 16, 2021, Ilé Ẹjọ́ Ìpínlẹ̀ Nizhny Novgorod fagi lé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́run tí Arákùnrin Sergey Verkhoturov pè. Ẹjọ́ tí wọ́n dá tẹ́lẹ̀ pé kó lọ lo ọdún mẹ́fà tó yẹ kó lò lẹ́wọ́n nílé ṣì wà bẹ́ẹ̀. Kò ní lọ sẹ́wọ̀n mọ́ lọ́tẹ̀ yìí.