Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

SEPTEMBER 4, 2020
RỌ́ṢÍÀ

Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn Ò Gbà Kí Wọ́n Tú Arákùnrin Christensen Sílẹ̀, Wọ́n Ní Kí Ilé Ẹjọ́ Tó Kọ́kọ́ Gbọ́ Ẹjọ́ Náà Tún Un Gbọ́

Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn Ò Gbà Kí Wọ́n Tú Arákùnrin Christensen Sílẹ̀, Wọ́n Ní Kí Ilé Ẹjọ́ Tó Kọ́kọ́ Gbọ́ Ẹjọ́ Náà Tún Un Gbọ́

Ní September 4, 2020, Ilé Ẹjọ́ Agbègbè Kursk fagi lé ìdájọ́ tíIlé Ẹjọ́ Agbègbè Lgov ṣe ní June 23 pé kí wọ́n tú Arákùnrin Dennis Christensen sílẹ̀. Ilé Ẹjọ́ Agbègbè Kursk wá pàṣẹ pé kí Ilé Ẹjọ́ Agbègbè Lgov jẹ́ kí adájọ́ míì tún ẹjọ́ náà gbọ́. Àmọ́ wọn ò tíì mú ọjọ́ tí wọ́n máa gbọ́ ẹjọ́ náà.