Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Láti apá òsì sí ọ̀tún: Arákùnrin Vadim Levchuk àti Arákùnrin Sergey Britvin lẹ́yìn tí wọ́n dá wọn sílẹ̀ lẹ́wọ̀n

DECEMBER 30, 2021
RỌ́ṢÍÀ

Wọ́n Ti Dá Arákùnrin Sergey Britvin àti Vadim Levchuk Sílẹ̀ Lẹ́wọ̀n ní Rọ́ṣíà

Wọ́n Ti Dá Arákùnrin Sergey Britvin àti Vadim Levchuk Sílẹ̀ Lẹ́wọ̀n ní Rọ́ṣíà

Ní December 30, 2021, wọ́n dá Arákùnrin Sergey Britvin àti Arákùnrin Vadim Levchuk sílẹ̀ lẹ́wọ̀n. Tẹbítọ̀rẹ́ ló wá kí wọn lẹ́yìn tí wọ́n dá wọn sílẹ̀. Ọdún mẹ́tà àti oṣù márùn-ún láwọn méjèèjì lò lẹ́wọ̀n.