Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JUNE 21, 2017
RỌ́ṢÍÀ

Fídíò Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Tó Ya Wọ Ibi Táwọn Ẹlẹ́rìí Ti Ń Ṣèpàdé ní Ìrọwọ́rọsẹ̀

Fídíò Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Tó Ya Wọ Ibi Táwọn Ẹlẹ́rìí Ti Ń Ṣèpàdé ní Ìrọwọ́rọsẹ̀

Ní May 25, 2017, àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà tó dira ogun ya wọ ibi táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń jọ́sìn ní ìrọwọ́rọsẹ̀ nílùú Oryol, ní Rọ́ṣíà.