Rọ́ṣíà
Gbé e jáde 121 - 135 of 191
Wọ́n Ti Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣúkaṣùka Lórílẹ̀-Èdè Rọ́ṣíà
Ní báyìí tí àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà ti fòpin sí àjọ táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń lò lábẹ́ òfin, àwọn Ẹlẹ́rìí àti ìjọsìn wọn ni wọ́n wá dojú àtakò kọ.
Àwọn Aláṣẹ Ilẹ̀ Rọ́ṣíà Fẹ́ Gbẹ́sẹ̀ Lé Ilé Tó Jẹ́ ti Àjọ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Ilé Ẹjọ́ Saint Petersburg máa tó bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ́ ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn lórí ẹjọ́ tí ilé ẹjọ́ kọ́kọ́ dá pé kí ìjọba gbẹ́sẹ̀ lé ẹ̀ka ọ́fíìsì àtijọ́ tó jẹ́ tàwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Rọ́ṣíà.
Àwọn Aláṣẹ Gbẹ́sẹ̀ Lé Gbọ̀ngàn Àpéjọ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Rọ́ṣíà
Kò ju ọ̀sẹ̀ kan lẹ́yìn tí ilé ẹjọ́ sọ pé àwọn máa gbẹ́sẹ̀ lé ẹ̀ka ọ́fíìsì àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà nítòsí St. Petersburg, tí wọ́n tún fi gbẹ́sẹ̀ lé gbọ̀ngàn àpéjọ wa.
Gbé e jáde 121 - 135 of 191