Rọ́ṣíà
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé Fẹ́ Sọ̀rọ̀ Síta Lórí Bí Ìjọba Ṣe Fẹ́ Fòfin De Ẹ̀sìn Wọn ní Rọ́ṣíà
Torí pé àwọn aláṣẹ ń halẹ̀ mọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà pé àwọn máa tó fòfin de ẹ̀sìn wọn ní Rọ́ṣíà, àwọn Ẹlẹ́rìí kárí ayé fẹ́ kọ lẹ́tà kí wọ́n lè ti àwọn ará wọn lẹ́yìn. Ìtọ́ni wà fáwọn tó bá fẹ́ kọ lẹ́tà yìí.
Kámẹ́rà Tú Àṣírí Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Bí Wọ́n Ṣe Fẹ́ Mọ̀ọ́mọ̀ Lọ́ Ẹ̀sùn Irọ́ Mọ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lẹ́sẹ̀
Àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà fẹ́ lọ́ ẹ̀sùn irọ́ mọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí lẹ́sẹ̀ nílùú Nezlobnaya kí òfin lè mú wọn ní agbawèrèmẹ́sìn.
Àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n Lágbàáyé Ò Fọwọ́ sí “Àyẹ̀wò Táwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n Ṣe” Láti Mú Àwọn “Agbawèrèmẹ́sìn” ní Rọ́ṣíà
Apá Kẹta nìyí nínú àpilẹ̀kọ alápá mẹ́ta tó dá lórí ohun táwọn gbajúmọ̀ ọ̀mọ̀wé nípa ẹ̀sìn, ohun tó ń lọ láwùjọ àti òṣèlú tá a fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò sọ àti ohun táwọn ọ̀jọ̀gbọ́n míì sọ, ìyẹn àwọn tó mọ̀ nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà ayé ìjọba Soviet àti lẹ́yìn tí wọ́n kógbá wọlé.
Àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n Ò Fara Mọ́ Bí Àwọn Aláṣẹ ní Rọ́ṣíà Ṣe Fẹ́ Fòfin De Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Apá Kejì nìyí nínú àpilẹ̀kọ alápá mẹ́ta tó dá lórí ohun táwọn gbajúmọ̀ ọ̀mọ̀wé nípa ẹ̀sìn, ohun tó ń lọ láwùjọ àti òṣèlú tá a fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò sọ àti ohun táwọn ọ̀jọ̀gbọ́n míì sọ, ìyẹn àwọn tó mọ̀ nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà ayé ìjọba Soviet àti lẹ́yìn tí wọ́n kógbá wọlé.
Ohun Táwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n Sọ: Ìjọba Ilẹ̀ Rọ́ṣíà Ń Lọ́ Òfin Agbawèrèmẹ́sìn Po Kí Wọ́n Lè Fẹ̀sùn Ọ̀daràn Kan Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Apá Kìíní nìyí nínú àpilẹ̀kọ alápá mẹ́ta tó dá lórí ohun táwọn gbajúmọ̀ ọ̀mọ̀wé nípa ẹ̀sìn, ohun tó ń lọ láwùjọ àti òṣèlú tá a fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò sọ àti ohun táwọn ọ̀jọ̀gbọ́n míì sọ, ìyẹn àwọn tó mọ̀ nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà ayé ìjọba Soviet àti lẹ́yìn tí wọ́n kógbá wọlé.