Ísírẹ́lì
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì
-
Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2,129
-
Iye àwọn ìjọ—32
-
Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi—3,835
-
Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún—4,731
-
Iye èèyàn—9,888,000
A Túbọ̀ Ń Wàásù Níbi Térò Pọ̀ sí Lórilè-Èdè Israel Bí Ẹgḅẹẹgbẹ̀rún Èèyàn Ṣe Ń Ṣèbẹ̀wò Sílùú Tel Aviv
Ní May 2019, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Israel sapá gan-an láti túbọ̀ wàásù láwọn ibi térò pọ̀ sí ní ìlú Tel Aviv.
Wọ́n Fi Ohun Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Là Kọjá Nígbà Ìjọba Nazi Hàn Níbi Ìpàtẹ Kan ní Tel Aviv
Wọ́n ṣe ìpàtẹ kan sí Tel Aviv káwọn èèyàn bàa lè mọ ohun táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà là kọjá nígbà ìjọba nazi.