Ítálì
Gbé e jáde 16 - 20 of 20
Wọ́n Fọ̀rọ̀ Wá Aláṣẹ Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Bollate Lẹ́nu Wò—Díẹ̀ Nínú Ohun Tó Sọ
Wo bí Gbọ̀ngàn Ìjọba àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà nínú ọgbà ẹ̀wọ̀n Bollate ṣe ń jẹ́ kí ayé àwọn ẹlẹ́wọ̀n dáa sí i.
Àwọn Aláṣẹ ní Ítálì Fàyè Gba “Gbọ̀ngàn Ìjọba” Nínú Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Torí Pé Ó Ń Ṣe Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Làǹfààní
Ohun tó mú káwọn aláṣẹ ọgbà ẹ̀wọ̀n Bollate ṣe bẹ́ẹ̀ ni pé wọ́n rí ipa rere tí ẹ̀kọ́ Bíbélì táwọn Ẹlẹ́rìí ń kọ́ àwọn ẹlẹ́wọ̀n ń ní lórí wọn, èyí tí wọ́n ti ń ṣe látọdún mẹ́tàlá sẹ́yìn.
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tu Àwọn Èèyàn Nínú Nígbà Ìwàásù Àkànṣe tí Wọ́n Ṣe Lẹ́yìn Ìmìtìtì Ilẹ̀ Tó Wáyé ní Ítálì
Kárí ayé ni àwọn Ẹlẹ́rìí ti ṣe ìwàásù àkànṣe kan, àmọ́ lórílẹ̀-èdè Ítálì, wọ́n ń sapá gidigidi kí wọ́n lè sọ̀rọ̀ ìtùnú fáwọn tí àjálù dé bá torí ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé ní àgbègbè Lazio, Marche àti Umbria.
Gbé e jáde 16 - 20 of 20