Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Jámánì

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Germany

  • 174,907

  • 2,002

  • 273,222

  • 488

  • 84,359,000

2019-04-04

JÁMÁNÌ

Ojúkò Àgọ́ Ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ Kan Ṣàfihàn Bí Wọ́n Ṣe Pọ́n Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lójú ní Jámánì

Ètò kan tí wọ́n ṣe láwọn ìlú ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní Jámánì ṣàfihàn bí ìjọba Násì àti ìjọba GDR ṣe pọ́n àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lójú nítorí ìgbàgbọ́ wọn.

2019-01-15

JÁMÁNÌ

A Ṣe Ètò Ìpàtẹ Kan Nílùú Kassel, Lórílẹ̀-èdè Jámánì Láti Ṣayẹyẹ Àádọ́rin Ọdún Àpéjọ Mánigbàgbé Kan Tó Wáyé Níbẹ̀

A fi ètò ìpàtẹ yìí ṣayẹyẹ àádọ́rin ọdún tá a ṣe àpéjọ mánigbàgbé kan, àpéjọ yìí ni àpéjọ térò tíì pọ̀ jù lọ táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe lẹ́yìn Ogun Àgbáyé Kejì.

2018-09-17

JÁMÁNÌ

Kì Í Ṣẹni Táwọn Èèyàn Ò Mọ̀ Mọ́: Wọ́n Ṣèrántí Max Eckert ní Ibi Ìrántí Tó Wà ní Àgọ́ Ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ Ìlú Dachau

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìwọ̀nba èèyàn ló mọ Arákùnrin Eckert tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, tó kú sí àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, ó ti wá dẹni tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí ọkùnrin tí ìgbàgbọ́ rẹ̀ fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin.

2016-11-17

JÁMÁNÌ

Ayẹyẹ Ìrántí Ọdún Tá A Dá Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Sílẹ̀ ní Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Brandenburg—Ọ̀rọ̀ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ló Dá Lé Lọ́dún Yìí

Láàárín ọdún 1940 sí 1945, àwọn Ẹlẹ́rìí tí wọ́n jẹ́ 127 ni wọ́n pa ní ọgbà ẹ̀wọ̀n tó wà ní Brandenburg an der Havel, lórílẹ̀-èdè Jámánì. Wọ́n sọ ìtàn wọn níbi ayẹyẹ ìrántí náà.