Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÁNÁDÀ

Àwọn Olùkọ́ Ìṣègùn Márùn-ún Nílẹ̀ Kánádà Sọ̀rọ̀ Nípa Ìtẹ̀síwájú Lórí Ìtọ́jú Tí Kò La Ìfàjẹ̀sínilára Lọ

Àwọn Olùkọ́ Ìṣègùn Márùn-ún Nílẹ̀ Kánádà Sọ̀rọ̀ Nípa Ìtẹ̀síwájú Lórí Ìtọ́jú Tí Kò La Ìfàjẹ̀sínilára Lọ

Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan lẹ́nu àìpẹ́ yìí, àwọn olùkọ́ márùn-ún tó lórúkọ nínú ìmọ̀ ìṣègùn sọ bí nǹkan ṣe rí nígbà tí wọ́n tọ́jú àwọn èèyàn láìlo ẹ̀jẹ̀.