Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

MAY 31, 2018
KÁNÁDÀ

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ní Kánádà Dá Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Láre

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ní Kánádà Dá Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Láre

Ní May 31, 2018, Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ní ilẹ̀ Kánádà sọ ìpinnu tí wọ́n fẹnu kò sí pé wọ́n fàyè gba àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà pé a lè yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́ láìsí pé à ń gbàyè nílé ẹjọ́. Inú wa dùn gan-an sí bí wọ́n ṣe dá àwọn ìlànà òdodo Jèhófà láre yìí.​—Aísáyà 33:22.

https://scc-csc.lexum.com/scc-csc/scc-csc/en/item/17101/index.do

Kà Sí I