Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

DECEMBER 25, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #9

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #9

Bí àrùn gbẹ̀mígbẹ̀mí yìí ṣe túbọ̀ ń ṣọṣẹ́, ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí ṣàlàyé ìdí tí kò fi yẹ ká dẹwọ́ láti máa dáàbò bo ara wa ká má bàa kó àrùn Corona yìí. A gbọ́ ìrírí méjì tó jẹ́ ká túbọ̀ gbà pé òótọ́ lohun tí wọ́n sọ.