Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JANUARY 29, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #1

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #1

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa, àwọn ìrírí yìí jẹ́ ká rí bí Jèhófà ṣe ń bù kún iṣẹ́ ìwàásù tá à ń fi ìtara ṣe láìka ti àjàkálẹ̀ àrùn yìí sí.