Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

APRIL 16, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #3

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #3

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí ṣàlàyé bí a ò ṣe ní máa ju “ẹ̀ṣẹ́” wa bí ẹni tó ń gbá afẹ́fẹ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí. Ó tún fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu àwọn ará mélòó kan.