Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

MAY 21, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #4

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #4

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí ṣàlàyé bí àwọn èèyàn Jèhófà ṣe ń “ja àjàṣẹ́gun” láìka bí nǹkan ṣe nira fún wọn tó. Ó tún sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa.