Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JUNE 18, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #5

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #5

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún àwọn ìdílé ní ìṣírí láti máa ṣe ohun táá jẹ́ kí wọ́n túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí. Àwọn òbí sọ ohun tí wọ́n ń ṣe láti jẹ́ káwọn ọmọ wọn sún mọ́ Jèhófà.