Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JULY 16, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #6

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #6

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fi dá àwọn àgbàlagbà lójú pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wọn, kò sì gbàgbé wọn rárá. Fídíò yìí tún sọ ibi tá a báṣẹ́ dé lẹ́nu iṣẹ́ ìkọ́lé ètò Ọlọ́run lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí.