Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

MARCH 28, 2018
MALAWI

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kọ Lẹ́tà Nítorí Àwọn Ará Wa ní Rọ́ṣíà​—Láti Màláwì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kọ Lẹ́tà Nítorí Àwọn Ará Wa ní Rọ́ṣíà​—Láti Màláwì

Gbọ́ ìrírí àwọn arákùnrin àti arábìnrin wa ní Màláwì, tí wọ́n kọ lẹ́tà nítorí àwọn ará wa ní Rọ́ṣíà. Àwọn kan sọ̀rọ̀ nípa ìgbà tí irú ohun tó ṣẹlẹ̀ ní Rọ́síà ṣẹlẹ̀ lórílẹ̀-èdè wọn, láwọn àkókò kan láàárín ọdún 1970 sí 1979.