Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Mexico

 

2018-05-08

MEXICO

Wọ́n Fi Ipá Lé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó Jẹ́ Huichol Kúrò Nílé Wọn ní Jalisco, Orílẹ̀-Èdè Mexico

Àwọn èèyàn wá gbéjà ko àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wọ́n sì lé wọn kúrò nílé. Wọ́n ti lọ bá àwọn aláṣẹ fún ìrànlọ́wọ́ kí wọ́n má bàa ṣe inúnibíni sí wọn nítorí ẹ̀sìn mọ́.

2018-04-10

MEXICO

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ṣe Tán Láti Bẹ̀rẹ̀ Àtúnṣe Sáwọn Ilé Tí Ìmìtìtì Ilẹ̀ Bà jẹ́ ní Guatemala àti Mexico

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìrànwọ́ láti ṣèrànwọ́ fáwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin tí ìmìtìtì ilẹ̀ méjì tó wáyé ba ilé wọn jẹ́ ní Mexico àti Guatemala.