MAY 31, 2013
ORÍLẸ̀-ÈDÈ AMẸ́RÍKÀ
Wọ́n Tún Ilé Ìwòran Stanley Ṣe
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó yọ̀ǹda ara wọn ti ṣàtúnṣe tó kàmàmà sí Ilé Ìwòran Stanley, ìyẹn ilé ńlá pàtàkì kan tí wọ́n ti ń lò fún nǹkan bí ọgbọ̀n ọdún láti ṣe àwọn àpéjọ àti ìdálẹ́kọ̀ọ́ tó dá lórí Bíbélì nílùú Jersey ni New Jersey.