Palestinian Territories
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Ilẹ̀ Palẹ́sínì
-
Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà—78
-
Iye àwọn ìjọ—2
-
Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi—213
-
Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún—72,237
-
Iye èèyàn—5,490,000
Wọ́n Ń Fi Ẹ̀tọ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tó Wà ní Àgbègbè Palẹ́sínì Dù Wọ́n
Wọn ò gbà láti forúkọ ẹ̀sìn àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sílẹ̀ lábẹ́ òfin torí wọn ò ka ẹ̀sìn wọn sí, ìyẹn wá ń jẹ́ kí wọ́n máa fi ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tí wọ́n ní dù wọ́n, kò sì yẹ kó rí bẹ́ẹ̀.