Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

APRIL 2, 2020
TAJIKISTAN

Wọ́n Fi Arákùnrin Jovidon Bobojonov Sẹ́wọ̀n Ọdún Méjì Lórílẹ̀-èdè Tajikistan

Wọ́n Fi Arákùnrin Jovidon Bobojonov Sẹ́wọ̀n Ọdún Méjì Lórílẹ̀-èdè Tajikistan

Ní April 2, 2020, ilé ẹjọ́ àwọn ológun tàwọn ará Tajik, tó wà ní ìlú Dushanbe tó jẹ́ olú ìlú orílẹ̀-èdè Tajikistan fi Arákùnrin Jovidon Bobojonov sẹ́wọ̀n ọdún méjì tórí pé ẹ̀rí ọkàn rẹ̀ kò gbà á láyè láti wọṣẹ́ ológun. Ó máa pe ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn.