Ohun Tuntun Wo Ló Wà ní JW.ORG?
ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI
March–April 2025
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Kí Ni Mo Lè Ṣe Táwọn Òbí Mi Bá Kọra Wọn Sílẹ̀?
Kì í rọrùn rárá táwọn òbí bá kọra wọn sílẹ̀. Àmọ́ wàá lè fara dà á tó o bá tẹ̀ lé àwọn àbá tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Kí Ló Dé Táwọn Òbí Mi Ò Fẹ́ Kí N Gbádùn Ara Mi?
Ka àpilẹ̀kọ yìí kó o lè mọ ohun tó lè fà á táwọn òbí ẹ ò fi ní gbà kó o ṣe ohun tó wù ẹ́, kó o sì tún mọ ohun tó o lè ṣe kí wọ́n lè máa gbà ẹ́ láyè láti ṣe ohun tó wù ẹ́.
ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ
Àwọn Ìdálẹ́kọ̀ọ́ Wo Ló Ń Mú Káwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Já Fáfá Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Wa?
Àwọn ìdálẹ́kọ̀ọ́ wo là ń gbà tó ń mú ká wàásù ká sì kọ́ni lọ́nà tó já fáfá?
LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA
Wọ́n Ń Sin Jèhófà Nìṣó Láìka Ìṣòro Àìlówó Lọ́wọ́ Sí
Nǹkan nira gan-an fáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà lórílẹ̀-èdè Philippines láàárín ọdún 1970 sí 1989. Ka àpilẹ̀kọ yìí kó o lè rí bí àpẹẹrẹ wọn ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ táwọn nǹkan àìròtẹ́lẹ̀ bá ṣẹlẹ̀ sí wa.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìdá Mẹ́ta Nínú Mẹ́rin Àwọn Ẹranko Inú Igbó Ló Ti Kú Láàárín Àádọ́ta (50) Ọdún—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì jẹ́ ká mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sáwọn ẹranko inú igbó lọ́jọ́ iwájú.