Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

OHUN TUNTUN

Apá Kìíní Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ti Wà Lórí Ìkànnì Báyìí

Apá Kìíní Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ti Wà Lórí Ìkànnì Báyìí

A ti gbé apá kìíní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì sórí ìkànnì jw.org. Ẹ̀kọ́ 01-12 ló wà nínú apá yìí. A máa gbé apá 2 sí 4 jáde láìpẹ́.

Ka apá kìíní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!