Apá Kẹrin Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ti Wà Lórí Ìkànnì Báyìí
A ti gbé apá kẹrin ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì sórí ìkànnì jw.org. Ẹ̀kọ́ mẹ́tàlá tó kẹ́yìn nínú ìwé náà ló wà nínú apá yìí.
Ka apá kẹrin ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!