Apá Kẹta Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ti Wà Lórí Ìkànnì Báyìí
A ti gbé apá kẹta ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì sórí ìkànnì jw.org. Ẹ̀kọ́ 34-47 ló wà nínú apá yìí. A máa gbé apá kẹrin jáde láìpẹ́.
Ka apá kẹta ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!