Apá Kejì Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ti Wà Lórí Ìkànnì Báyìí
A ti gbé apá kejì ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì sórí ìkànnì jw.org. Ẹ̀kọ́ 13-33 ló wà nínú apá yìí. A máa gbé apá kẹta àti ìkẹrin jáde láìpẹ́.
Ka apá kejì ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!