Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

FEBRUARY 20, 2018
OHUN TUNTUN

Bíbélì Àtẹ́tísí​—Ìwé Róòmù Ti Wà Lórí Ìkànnì

Bíbélì Àtẹ́tísí​—Ìwé Róòmù Ti Wà Lórí Ìkànnì

A ti ka ìwé Róòmù sórí ẹ̀rọ látinú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe, ó sì ti wà lórí ìkànnì jw.org.

Tẹ́tí sí ìwé Róòmù.